AWON AGBAAGBA ILU OGBOMOSO DIDE LORI ORO IMAM, WON SE IKILOTO LAGBARA FUN

  Рет қаралды 5,551

ARABA TV.

ARABA TV.

Ай бұрын

AWON AGBAAGBA ILU OGBOMOSO DIDE LORI ORO IMAM, WON SE IKILOTO LAGBARA FUN

Пікірлер: 24
@user-mi5lw8sj9v
@user-mi5lw8sj9v Ай бұрын
Hello, E Sora Fun Oro Esin, Oro Esin Papajulo Esin Musulumi Ti Fe Ba Ohun Rere Ile Yoruba Je... Awon To N'pin Rice Fun Pe Ko Ma Fi Fa Wa Oju Rere Awon Eniyan Ni Alatileyin Re... Akoko To Ki Yoruba Dide Fun Eto Won... Ise Awon Elesin Okeoya Lo N'lo...
@uniquebabybabygirl5640
@uniquebabybabygirl5640 Ай бұрын
Awon baba dada agba yin a dale e dabi awon afenifebi ti won npe ra won ni afenifere
@kunmimarvelous5795
@kunmimarvelous5795 Ай бұрын
E yo imam ofo , imam oloribuku......
@ojogabriel3627
@ojogabriel3627 Ай бұрын
Eyin Baba yi,yio dara fun yin pupo. E seun pupo, E ku atunto... Awon Muslim lo nda orilede Nigeria ru,won ki gba f'olorun afi ki won fi ija ati wahala se gbogbo nkan.
@maryogunkuade2560
@maryogunkuade2560 Ай бұрын
Àwọn àgbà tí ayé wọn máa dára. Nígbà ti wọn kìí ṣe àwọn ará Iwọ ti ẹnu wọn kò ká Mufti.
@user-mi5lw8sj9v
@user-mi5lw8sj9v Ай бұрын
Hello : Iromi To Njo Lori Omi, Onilu Re Nbe Ni Isale Odo, Awon Alakatakiti Esin Inu Musulumi Lo Wa Leyin Re... E Ti N'wo Asoju Satani Larin Yin, E Tete Wa On@ Bi E Se Ma Dapada Si Ibiti O Ti Wa, O Wa Jale Ohunolohun Ni....
@uniquebabybabygirl5640
@uniquebabybabygirl5640 Ай бұрын
Imamu japa lo si saudi ile yoruba ni ogbomosho nje
@ojogabriel3627
@ojogabriel3627 Ай бұрын
Let that lemanmu go to mecca and do his wash , Se e lagbara lati yo lemanmu ni, E le danu... So lagbara ju yin lo ni? Awon ore Fulani, Iran oluwo...
@user-py6jt5og4m
@user-py6jt5og4m Ай бұрын
EKU OHUN BABA, AWON ALALE AAGBE YIN O. OGBOMOSO O NI BAAJE. OLODUMARE MA BA WA SEGUN O.
@leahayodele2526
@leahayodele2526 Ай бұрын
ARIFIN NI ELEYI FUN OBA ATI.ARA OGBORIELEMESO.ILU ATIJO
@waleikujuni9463
@waleikujuni9463 Ай бұрын
Imagine, ordinary imam, disrespecting the His Imperial Majesty, the King of Ogbomosho. Arinfin ati Iwosi nla re. Won ti so ori aiye ko do.
@estherewetuga8245
@estherewetuga8245 Ай бұрын
A dupe lowo awon baba wa , e ku ohun sir
@leahayodele2526
@leahayodele2526 Ай бұрын
OGBOMOSO KONI BAJE LAGBSRA OLORUN OLUWA YIO BA SATANI WI..
@elizebethfoluke6483
@elizebethfoluke6483 Ай бұрын
Imam Ko Pada Si Mecca. Bishop Ko Pada Si Rome. G.Os Japa Si Jerusalem. Isedale Yoruba Ni Oba. Kabiyesi ooooooo.
@uniquebabybabygirl5640
@uniquebabybabygirl5640 Ай бұрын
Awon Muslims wonyi ko ni itiju rara kilode ti won fi ma nda wahala sile ni gbogbo agbaye bayi wan ti brainwashed gbogbo won what a shame
@johnakinbobola4539
@johnakinbobola4539 Ай бұрын
Why can't Ogbomoso remove the Imam?
@sunshinesm5657
@sunshinesm5657 Ай бұрын
O ku Mufti ti ilu iwo naaa. Ta ni baba re ni ile yoruba. Ki awon ara ilu iwo na dide ki won si pe mufty ti ilu iwo naa ki won beere tani baba re 3rd generation nilu iwo.
@uniquebabybabygirl5640
@uniquebabybabygirl5640 Ай бұрын
❤❤❤
@seewarcrownlarryarocotunde7662
@seewarcrownlarryarocotunde7662 Ай бұрын
ESU is our father, please stop using ESU as your satani or devil…imam is being used by devil or satani…not ESU
@user-jk9zo8vu4h
@user-jk9zo8vu4h Ай бұрын
We don't hear u sir
@user-py6jt5og4m
@user-py6jt5og4m Ай бұрын
KO DA, EMI O RO PE OMO OGBOMOSO NI OMOKUNRIN NA. ALARIFIN NI OMODE NA. KO WA BI GBA LO. NIBO NI AGBO ILE BABA TI E. A MA DUPE PE OHUN KO NI OKOKO GBA PHD NI ILU OGBOMOSO.
@topeamaka7806
@topeamaka7806 Ай бұрын
All the people of ogbomosho now are seeing what is going on and the most painful part is the muslum brothers refuse to reveal the truth of the matter to the people of ogbomosho but mark my word dont be surprise when they will bring somebody from a Christian home let me say a pastor and dey will brain wash u guy again for him to be imam
@uniquebabybabygirl5640
@uniquebabybabygirl5640 Ай бұрын
Awon baba dada agba yin a dale e dabi awon afenifebi ti won npe ra won ni afenifere
13 States Rush To Hold Council Polls After Supreme Court Judgment
18:12
TVC News Nigeria
Рет қаралды 3,5 М.
Full Story Behind Ogun O Jalu Ogbomoso
28:13
AIF YORUBA CULTURAL CENTRE
Рет қаралды 7 М.
What it feels like cleaning up after a toddler.
00:40
Daniel LaBelle
Рет қаралды 28 МЛН
Was ist im Eis versteckt? 🧊 Coole Winter-Gadgets von Amazon
00:37
SMOL German
Рет қаралды 39 МЛН
ISOKAN OGBOMOSO (UNITY OF OGBOMOSO) BY IMAM AGBA OFFA WITH SAOTI AREWA
1:01:48
Topic: Knowledge and its Benefit (IMO ATI OLA TO MBE FUN)
59:40
Daaru Naim
Рет қаралды 2,3 М.
Sunrise Daily
1:59:41
Channels Television
Рет қаралды 3,2 М.
MY FATHER'S ONE WEEK OBSERVATION EEII EWIASE MMMMMMM
19:07
O SELE! OLUWO WO GAU!! WON JAWE GBE'LE LE OLUWO LOWO...
30:03
ARABA TV.
Рет қаралды 1,3 М.
EJE KA GBADURA PELU PROPHET SAM OLU ALO
2:12:14
Prophet Sam Olu Alo JP.
Рет қаралды 7 М.
Помог🤣#сериалы #фильмы
0:28
Кинокомбо
Рет қаралды 1,9 МЛН
Приятного аппетита 🤣
0:15
Dragon Нургелды 🐉
Рет қаралды 2,9 МЛН
tom and Jerry 😱🆕 #trending
0:23
Nemi Shorts
Рет қаралды 14 МЛН
Бушмен и бабуин. В поисках воды.
0:42
BERMUDA
Рет қаралды 4,8 МЛН
え、、、!
0:11
美好秋人
Рет қаралды 7 МЛН
покупки за продуктами сейчас вс раньше
0:23
Fun Fun TV short film: 🙏baby save water😍
0:28
Fun Fun TV
Рет қаралды 3,6 МЛН