#sundayigboho #yorubanation #ganiadams Ha!! OKODORO ORO, EWAGBO OHUN OKUNRIN YI SO NIPA AARE GANI ADAMS, AARE LAAJI ABASS ATI SUNDAY IGBOHO
Пікірлер: 73
@jamesshall51604 ай бұрын
Omo Alhaja! My man comes on air once in a blue moon but when he makes appearance, he spit fire! God bless you. You are absolutely correct!
@ModupeolaBello-zi2yw4 ай бұрын
Ododo Oro le UN so my brother ekulakaye Opolo yin Koni joba laseeedumare one love ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️
@bolajiolaleye26444 ай бұрын
Sunday Igboho is the man of the moment
@olubunmiogundele23554 ай бұрын
I just love this guy ,he spit wisdom anytime he comes online.
@ashimolowoqasim48174 ай бұрын
Correct 💯 ,l ❤u my brother God bless u
@ModupeolaBello-zi2yw4 ай бұрын
Ododo Oro le UN so Ote ti poju ni ILe YORUBA ejeki Afi OWO so wo Po koleda fun gbogbo wa EKU Ohun my brother OLORUN OBA a ma wa pelu yin oooooo one love ❤️❤️❤️❤️
@tiendatienda37234 ай бұрын
God bless you my brother, you are right...
@samsonusman2624 ай бұрын
My brother GOD bless you for the truth you are saying
@ModupeolaBello-zi2yw4 ай бұрын
Awon Foolani to wa ninu gbo ni aso pe ki won le kuro ninu Igbo wa. ASE ASE ASE ASE ASE ASE Edunmare OLORUN OBA Koni Fi e SI le laseeedumare one love ❤❤❤
@akinladeemmanuel39674 ай бұрын
Good evening my dear brother oduduwa a gbe wa ooo ase Yoruba nation no going back
@SundayBamisile-ri3zn4 ай бұрын
Good talk my brother, God bless you and your family. Great Yoruba Nation God bless YN. Thanks my brother. Happy new week, take care and remain bless Sir.
@mamaosun35874 ай бұрын
Ki Are Gani Adams, ma pa itankitan nipa Yoruba mo. Ko ma da ori itan Yoruba ru. Awon Omo to mbo lehin o fe ko itan iro.
@feliciaaremu94244 ай бұрын
Oti to oro ni brother yi so fun awa omo Yoruba 🎉🎉God bless you sir
@oluwasesanajayi22984 ай бұрын
Respect Baba mi
@comfortfamiwagun6714 ай бұрын
This man u talk true to them gbogbo awon alabosi maa da atibaba ni I Mo gbe gbosa fun Okunrin yii Lakaye re ko ni baje O see Omo
@adebowaleismailabiodun74394 ай бұрын
Amin brother mi
@modupeadegboye50794 ай бұрын
Real truth.Your wisdom and knowledge will continue to increase.Keep on saying the truth
@oriirenitemitv67274 ай бұрын
T'oba je wipe gani Adams se ojuse rẹ gẹgẹ bi o ti tọ ni ti òun náà respect ipo towa pẹlu awon to fije oye ti o sí feran Iran yoruba ni tooto awon nkan to nsele yi koni sẹlẹ lati ojo ti wahala ti nsele káàkiri ipa wò ni gani Adams gbe he said he's model aare by him self but gani Adams nṣe ilara Sunday Igboho it's shows in his speech and and actions gani Adams and his followers need to straight themself Sunday Igboho never disrespect anyone much love for Igboho oosa
@kehindeadeyemoadeyemi30904 ай бұрын
God bless u my gr8 anchor.
@waleasylumoba67014 ай бұрын
Well done 👍
@bettylusi5844 ай бұрын
Otito lo so Olorun a je ko gbo God bless you
@risiashiru55534 ай бұрын
True talk
@BandaniansTv-sg1hn4 ай бұрын
God bless you my brother
@mnbbmnnbb4 ай бұрын
Eyin egbe mi e fi iwa Ika ati ote sile amen
@NwokoroEmeka4 ай бұрын
Thank buddy God bless you
@user-xg3rw3pp4w4 ай бұрын
My dear looto gani Adam timi igberaga ju,,
@olanrewajuowoyemi70224 ай бұрын
Good talk
@AyoolaAyepola-uu5zb4 ай бұрын
You are always on points my broda. Keep it up
@craftdrena88374 ай бұрын
Bless up
@toyinorry46594 ай бұрын
CORRECT 👍
@kehindeadeyemoadeyemi30904 ай бұрын
All ur statements are truthful and reality.
@aladesakiru64334 ай бұрын
O ga oo.otito oro ni brother mi Yi so.kini kan wa ti koye awa omo yoruba.o di igba ti a ba pa awon odale Yoruba diedie .ki Yoruba to losi waju.tori wipe odale ti bimo to po.yoruba*3
@waleikujuni94634 ай бұрын
Before the table turns to the Hausa/Fulani as regards farming. They depend on us for food. But all the Fulani President that rules Nigeria 🇳🇬 so far developed irrigation farming and pushed all the fertilizers and tractors to the North at the expense of the south.
@adebayoaborishade-zp1tt4 ай бұрын
Did All our SouthWest Leaders have a clue of this Logic? All wat dey know is to use their Constituency Allowance & Allocations to be buying Houses home & Abroad,it's a Pity though😙🤔
@MrOgom4 ай бұрын
Wow you nailed it, I hope they are listening United we stand, divide we fall yoruba ronu wo.
@risiashiru55534 ай бұрын
Ododo oro
@mamaosun35874 ай бұрын
Ma dahun. Awon onijekuje, abifun radarada, obe leba, awon alajeku. They should start planting around the house.
@oladojaodunsi76144 ай бұрын
Please listen more carefully to this man to see that he points out that Yoruba needs to look deeper into the harmonious living philosophy of the fore-bearers the Yoruba, called "omoluabi" so it could be developed to be used for the enhancement of harmonious development of modern day Yoruba. Alaafia
@KehindeoseniSaliman-ou4jt4 ай бұрын
Brother mi Yi ni opolo pipoju ooo
@samueladeyemi69424 ай бұрын
Adamu is just a jealous man bro, Aare is jealous of Igboho. He won't do it and he doesn't want Igboho to do it. Let him go nd sit down jor. Enu lasan ni Gani ni...o leso itan 200 years sile
@Ola-uq8yf4 ай бұрын
You are making sense brother
@olatundeagbaje25504 ай бұрын
Won ma shey Ara won ni, oti sure juuu
@modupeadegboye50794 ай бұрын
Ori e pe ju omo iya mi,omoluabi atata.Gbogbo epe too Se fun awon Fulani t ni yoo mo won timo timo bi eti Se mo orii.Tesiwaju lati maa so ooto.Olorun a maa wa pelu.Oro nla lo so,to si wumi lori pupo,O see ooo
@terryo49364 ай бұрын
We don't care about the title but your responsibility. Ganiyu is not doing his job.
@hassanyusuf16554 ай бұрын
Brother let them know jare story lason lason ni won ma unso lojojumo
@MrBajos-ce9by4 ай бұрын
Ganiyu Adamu will never seize to be OPC leader because that's the source of where he get's money from.
@isaacstrongtower-ws9qm4 ай бұрын
W I S D O M.
@funmishobowale49584 ай бұрын
Ododo oro ni ogbeni yi nso o
@adeoladesmond44214 ай бұрын
Confirm u are right but aare can’t live OPC cos aare is still looking for money
@user-mi5lw8sj9v4 ай бұрын
Gbogbo Arekereke Awon Fulani Ni Lati Le Gbogbo Yoruba Danu,, Niwon Igbati Won Ti Pa Oba Merin Ni Ile Yoruba Ti Onakakanfo Si Wa Laye, Aroko Ni Fun Wipe Are Lasanlasan Ni, Ko Ja Mo U'nkankan... Ekeji Awawi Ti Ko Ni LAKAYE Ni Onakakanfo N'so... Se Awon To N'hu Iwa Ika, Pa Agbe, Fi Eran Jeko, Pa Omo Pa Ijoye Pa Oba Gba Ase Lodo Ijoba? " Dajudaju Alaesodo Ni Are Ati Gbogbo Awon To Ko Lati So Fun.... Eri Okan Re Kukuku N'so Fun.... Sunday Igboho Lo N'dode Kiri Ati Awon Egbe Re To N'paro Fun..
@olusolaayindefakeye44264 ай бұрын
Ododo oro. Sorosoro wa, ogbon ati oye a ma je ti yin o.....E seun
@arinolamayaki74874 ай бұрын
Gani Adams o fe se nkankan ni ile Yoruba, o fe fi Yoruba pa owo ni. O si ni igberaga pupo ju si awon Oba. Igboho Oosha ni iteriba ati ilosiwaju ile Yoruba lo je Oloye logun. Gani Adam ni ki awon oba lo mu 20b wa ki oun to le ja fun ile Yoruba, kini iwulo oye kakanfo to je. O fe fi Yoruba ta oja ni. Omo Adeyemo o bere kobo lowo enikeni. O nja fun iran Yoruba ni. Iyato to wa larin Oloye Sunday Adeyemo Igboho Oosha ati Gani Adam yato patapata.
@flipzkyky63564 ай бұрын
You’re talking about respecting Gani Adams. Do you even know he greets OONI of IFE while standing. Respect is reciprocal
@abiodunakanbi73434 ай бұрын
Oye olori olode
@ismailabidemi11844 ай бұрын
Biwon koba gbe ohunje wa se ohunje won ma baje nani gbese si mase lule fun won nani
@gsjhsgshsusbbgshshshsjs57034 ай бұрын
Ooto Oro niwon Omo deyi unso olo made lagbe orie akanoke peju ASE edumare
@sikirutijani76354 ай бұрын
Ganim Adams will not the leader of OPc to anybody because of the money.
@MoshoodLateef4 ай бұрын
Ninu awon to ti n soro lori ero ayelujara iseyi ni mo nife si ju ise opolo ni,olorun yoo maa teyin si waju
@gsjhsgshsusbbgshshshsjs57034 ай бұрын
Agbo ninu itan Yoruba wipe oloye toju are onakakaunfo odabipe onikoyi
@kehindejosephkashimawo94104 ай бұрын
Ounje wo ni Fulani ngbe wa?/ Sebi won nse businesws nui,, abi ofe ni won ngbe food items wa.. ?? Se orileede niyen? Se orileded to wa ni isokan niyen ? Ki apa kan maa wipe awon o ni ta oja fun apa keji mo,, OIpolopo yuin o siu fura wipe Orileede ko la wa yui.. A kjii se okan naa rara.
@omooluabiyoruba1044 ай бұрын
Very very sensitive words, I like you for this sensitive words but gani adams will never agree with you, because he wants to be first, Second, etc Aree ops, opu, olokun, etc gani wants everyone to be under him……. He is the president of all associations he belongs to
@uniquebabybabygirl56404 ай бұрын
But gani must respect himself talo omo gani baba laaji abass is not his mate he is too arrogant and self centered person and very rude
@vickyyorubanationnownogoin87874 ай бұрын
Areonakakanfo oye olori eso aalafin ni ko ni ikankan se pelu itan yoruba inka to je oye lelori ni ki o se
@taiyeajiboye39684 ай бұрын
Are ona kakanfo Gani Adam oun gan ni ko se suru nitori ipo agba wa lowo re.ki Gani Adam di Atitan ni ile yoruba,gbogbo egbin ni agba ma gba. Ile yoruba ko ni baje.e parapo ki e di eyokan.
@kemoblunsky37944 ай бұрын
GANI adams ti fe pa awon omo yoruba tan o, afi oro sha bi werey, GANI adams doesn't fit that tittle, he needs to accept that he is a failure, ko se, ko fe keni to fe se se.
@makokin214 ай бұрын
Are Gani have never been able prove to us that he is Yoruba and which side he is standing ,they kept attacking igboho for defending the Yorubas,asiri awon OPC ma to tu,won ro wipe awon po ju ile Yoruba lo ni,oju won ma to ja laipe,