We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
Пікірлер: 31
@user-vv3cy4jg4w26 күн бұрын
Ijoba kose ma bawon da malu won kiri rara reluway ko Motorola ni igba tojewipe awon ijoba malu ni dari Nigeria titi di oni awon weere ekuku ni sowadi malu bi yin ni Nigeria yii up Yoruba nation 🤲🤲👍👍
@josephmaito21326 күн бұрын
Aiye yin koni da
@mariamasie932926 күн бұрын
Eto wa fun Malu ko si eto fun eniyan,Omase oo
@lukmonolamilekan861626 күн бұрын
Ok fulani nikan loni Nigeria yi abi o dabi pe oloriburuku ni gbogbo yin
@ElishaOlasomi-fx3wx26 күн бұрын
Kini oun ti o kan ijoba kan malu
@timothywale805526 күн бұрын
Oti dandan ki malu ma wo reluwe , tani iba a tun wo reluwe bi kose malu , koda first class ni kiwon joko si ,pelu iroru gbendeke 😂
@bigbirdrewire25 күн бұрын
AYE awon FULANI ATI AWON IJOBA TII BAJE
@moriyamooyenuga665626 күн бұрын
SE RELUWE TI WON FI NKO ENIYAN NAA NI WON MA FI KO MAALU NAA
@agbekeaiyedun710726 күн бұрын
Hummmmm 😂
@akinniranyeomolayo163223 күн бұрын
Wahala ti yin niye Ika county
@adelekeaduke339126 күн бұрын
Kada fun ijoba Nigeria Oloribuku ni ijoba Nigeria 😂😂😂
@fatalkehinderaheemat151325 күн бұрын
Is batter emi eniyan bale ni ilu now awon fulani ti apa eniyan si ilu nitori pe won da malu kiri ori lede awon agbe yo simi Walala awon Fulani ooooo o da ye ooo
@peterfernandez751126 күн бұрын
Lati lo ma je oko lo oko
@idrisalooma512026 күн бұрын
Tiwonbarise oo nkan todarani
@KEHINDEGBAKINOLA-xp4rw25 күн бұрын
😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂otilo
@omitoogunpeter382325 күн бұрын
"ILU AWON ERANKO" Tabi oruko wo ni ki a fun ilu ti awon alase ijoba ti feran emi malu ju emi awon omo eniyan lo 😢 ?.
@lawalomolara603026 күн бұрын
We're.ni gbogbo yin
@kemoblunsky379424 күн бұрын
Tinubu, ha, o ma se o,afigba to so awa eya toku di eru fulani.
@jamiuafolayan922126 күн бұрын
Hope is not for free oo
@oldmanindubaivillage422226 күн бұрын
Now we all see the reason why they can't stop them not to disturb the peace of the citizens,this is government business not individual at all ,if not the will not use railway that's meant for the citizens for cow ,all our politicians re cows that's why they value cow life than human beings.never expect good things in that country call Zoe
@adekunle__akinpelumi976_26 күн бұрын
It's better
@abeylovecomediantv77125 күн бұрын
Fulanigeria 🤪🤪🤪
@sundayakindunbi579626 күн бұрын
To use railway to carry cows from one place to another is not the last SOLUTION
@kyrieeleison706525 күн бұрын
Is fulani the only tribe that we have in Nigeria? This is so hypocritical!
@olufelabarber779526 күн бұрын
Ibo ni fulani fe ju inu oko oloko lo ? Ijoba gan raye., emi otiri ibi tijoba t nba awon e iyan ko malu won kakiri ri. Nigeria yi nikan na . Money and energy wasted
@adejokesebastian909525 күн бұрын
E funra oo no checking point ooo anything can be maluu oo
@adeyemoademolajammy200226 күн бұрын
Se maalu naa le so di nkan gidi bayi, ni ibi ti ebi ti npa awon eeyan bayi, se awon ajoji odaran le so di eeyan gidi bayi?