O MASE OO WON DAJO IKU FUN AWON MARUN NI OSUN STATE NITORI FULANI HERDERSMEN, IRU COUNTRY WO LEYI

  Рет қаралды 8,979

YEYE DARA KOWEE TV (kokoko)

YEYE DARA KOWEE TV (kokoko)

6 күн бұрын

ADAJO AGBA PASE KI WON YEGI FUN AWON MARUN NILU OSUN STATE NITORI FULANI HERDSMEN......SUGBON WON KO BIKITA NIPA OPOLOPO OMO YORUBA TI AWON FULANI TI PA SORUN ABI S#AYE.

Пікірлер: 155
@tayoadedara9100
@tayoadedara9100 4 күн бұрын
People need to rise up and fight for their right.
@ogoatiagbara1
@ogoatiagbara1 4 күн бұрын
Oloriburuku ni adajo to da ejo iku fun Omo Yoruba
@ceciliaakindunbi654
@ceciliaakindunbi654 4 күн бұрын
Eniti o da ejo yen ki awon naa lo pa nitori o wu bi awon fulani se npa omo Yoruba .Ogun aye ati ti orun lo maa pa lojiji ti ko ba da awon wonyen sile
@isaacstrongtower-ws9qm
@isaacstrongtower-ws9qm 4 күн бұрын
BUHARI IS STILL IN POWER. SHAME TO THE GOVERNORS IN YORUBA REGIONS.
@veronicaaduVBA
@veronicaaduVBA 4 күн бұрын
👍 👍 👍
@bukolayussuf862
@bukolayussuf862 4 күн бұрын
What a country!
@kehindepeter7138
@kehindepeter7138 4 күн бұрын
Nigerians are fighting to become citizens in there country. Where one tribe is more Nigerian than the other. I wept for Nigeria.
@reusamanda9758
@reusamanda9758 4 күн бұрын
Thought you said Yoruba are senior citizens 😂😂
@veronicaaduVBA
@veronicaaduVBA 4 күн бұрын
HMNMN! ONE TRIBE IS MORE SUPERIOR THAN OTHERS IN NIGERIA OR BETTER STILL ZOOGERIA.
@minebloxgamez5220
@minebloxgamez5220 4 күн бұрын
Amin o 🙏 gbogbo won oniku sibi ti aso won wa...
@user-qw3bc6dj5v
@user-qw3bc6dj5v 4 күн бұрын
Thanks for this video YEYE DARA KOWEE KO KO KO. Oṣun State people should protest. They should go to their House of Assembly and trouble them.
@modupekosoko1176
@modupekosoko1176 4 күн бұрын
Olofo Adajo
@adenikeadeyemo2133
@adenikeadeyemo2133 4 күн бұрын
Awon Oba ti Fulani pa se won dajo iku fun won Olorun a da fun gbogbo won
@veronicaaduVBA
@veronicaaduVBA 4 күн бұрын
👍 👍 👍
@bunmiodusina-idollor3479
@bunmiodusina-idollor3479 4 күн бұрын
This is really unfair! That judge didn't do well at all!! So when will YORUBAS get JUSTICE for all the atrocities that the BOROROS have done against them??!
@Aworawo
@Aworawo 2 күн бұрын
As bad & unjust as this case may appear to be, the judge is not to blame, but the law. Judges decide based on the evidence at their disposal = as the lawyers argue before them. This means incompetent lawyers can mishandle your case, whereas a good lawyer can save your head, even if u did the crime. Judges can not ring their sentiments or what they know about d cases to bear - only what the lawyers argue. This is the paradox of the Western legal system that we are practicing: can send d innocent to jail or death, & let d criminal off. However, there's always a political dimension to these kinds of cases. Osun State Governor (as well as the President, if it is a federal case) has the prerogative of mercy & the power to commute sentenses, or even grant unconditional clemency. Buhari's govt. (Fulani-led govts.) was probably abusing this power to free all the Fulanis arrested & never charged. So don't cruxify d judge. Blame our lame-duck governors, emaciated Yoruba Obas, & selfish Yoruba politicians.
@olayinkaadesina1394
@olayinkaadesina1394 4 күн бұрын
Yeye Dara Adajo yen ma tun ejo da ni omo yoruba koni gba, won ma tun ejo da ni o.
@babalolakutedo5592
@babalolakutedo5592 4 күн бұрын
Omo ale poo ninu yoruba
@reusamanda9758
@reusamanda9758 4 күн бұрын
How sure are you that you’re not omo ale? We’ll believe until you conduct a DNA test of yourself
@kingsglory100
@kingsglory100 4 күн бұрын
Very sad 😭
@goldsilver545
@goldsilver545 4 күн бұрын
Otio koje je be. Adajo oloriburuku ni kii se omo Yoruba. Yorubas should not allow this injustice. Those 5 people should be vindicated immediately.
@margaretalonge1220
@margaretalonge1220 4 күн бұрын
This is getting out of hands. In the country where God gave us everything
@olumuyiwakehinde929
@olumuyiwakehinde929 4 күн бұрын
Adeleke gan ti wo Gau. Olorun
@folashadetaiwo939
@folashadetaiwo939 3 күн бұрын
God bless you Yeye Dara, ejo se adajo yi kori opolopo ogulogo awon omo Yoruba ti won ti pa ni, adajo yi ko gbodo ri be oo, ki eya se noma, awon fulani yi nse orisi risi ti ko dara rara fun awon agbe nipa maluu ti won nko je oko awon agbe wa, ti won atun pa agbe na sinu oko won, SE O DA BEEE? Ha Omo Adeyemo igboho osha owo baba Dmin kudos to you CSI, Yeye Dara kudos to you mama alanu gbogbo mekunu
@princeade9082
@princeade9082 4 күн бұрын
Omo yoruba maa yegi fun adajo yen ni
@Ibo22272
@Ibo22272 4 күн бұрын
Olori ibu ni awon kan ninu awon agba Yoruba won Fi awa omo Yoruba lobi lodo awon fulani olorun oba yio je gbogbo won niya
@olusolaayindefakeye4426
@olusolaayindefakeye4426 4 күн бұрын
Yoruba ! Yoruba!! Yoruba!!! E ronu ,ki e si ranti atunbotan. Ejo buruku ni eyi ti eyin Adamo da yi o
@adenijiajewole7998
@adenijiajewole7998 4 күн бұрын
Governal ko gbudo fi owo si iru ldajo baye ooo ,
@bolanlekemi6903
@bolanlekemi6903 4 күн бұрын
Ni gba ti awon fulani pa Debora awon melo ni Yoruba pa nigba ye Adajo ye mari ibinu Olorun oba faaaa
@user-lo7jy9jf4h
@user-lo7jy9jf4h 4 күн бұрын
Amnesty ni won fun fulani apayan ooo fulani pa eyan won fun ni amnesty abi ki la fe se si bayi. Adajo wa dajo iku fun awon omo yoruba tori won pa fulani kan. Haa olorun ma da fun yin ooo nibo le fi eti ati oju si nigbati fulani npa omo yoruba adabi a da fun yin oo
@margaretalonge1220
@margaretalonge1220 4 күн бұрын
Amin
@OluwatobiAdunni
@OluwatobiAdunni 4 күн бұрын
God have mercy on us in Yoruba land
@olumuyiwakehinde929
@olumuyiwakehinde929 4 күн бұрын
That's why they're after CSI
@olumuyiwakehinde929
@olumuyiwakehinde929 4 күн бұрын
Yoruba nation ni solution wa ooo. Yeye Dara.
@pst.mo.8243
@pst.mo.8243 4 күн бұрын
AMIN ASE TO YOUR PRAYER DEAR SISTER 🙏🏼🙏🏽🙏🙏🏿🙏🙏🏿🙏🏼
@olurantiosadare1873
@olurantiosadare1873 4 күн бұрын
Very sad! Adajo na Olorun ada adajo na lejo iku loruko Jesu.
@Faeexcq
@Faeexcq 4 күн бұрын
Ase ti gun
@user-bq5br8jq9u
@user-bq5br8jq9u 4 күн бұрын
You do not respect that type of judge, he is going to face the same penalty in the name of jehovah, shame on all yoruba governors if they did not questioned that of judge, please allow the governors say something about this case PP michael.
@fehintolacomfortsolesi6519
@fehintolacomfortsolesi6519 3 күн бұрын
Yeye Dara, opolopo Yoruba Ni won ni awon. Malu yen. Ti. Awon Fulani nsin yen oooooh.
@afusatarowolo2268
@afusatarowolo2268 3 күн бұрын
HMMM OGAAA OOO OMASE OOO OLOHUN ASE IDAJO GBOGBO WON INSHA ALLAH
@adenikefajuke5994
@adenikefajuke5994 4 күн бұрын
Ki Adajo naa ya tetefi ile Yoruba sile.
@oluremiabioye7877
@oluremiabioye7877 4 күн бұрын
Haaa eleyi lagbara o. Iru adajo wo leleyi .Olorun sanu wa o.
@AyotundeOlaoye-wg4bi
@AyotundeOlaoye-wg4bi 4 күн бұрын
Yoruba ronu isu kan 10,000 naira. inkan ti sele si yoruba.
@KehindeoseniSaliman-ou4jt
@KehindeoseniSaliman-ou4jt 4 күн бұрын
Yoruba nation no going back Yoruba nation nikan Nan ni ONA Abayo fun gbogbo Ile Yoruba patapata ooo
@AyotundeOlaoye-wg4bi
@AyotundeOlaoye-wg4bi 4 күн бұрын
Ani ki Yoruba dide ki won ja fun ara won sugbon won o dawa. loun.
@MrPany10
@MrPany10 Күн бұрын
Well-done ma, God bless you and your family. Point of corrections. This incident in Osun state is between Fulani's Father and Son, the son arranged to kidnap his father because the father failed to settle him money and cows. Those people arrested and prosecuted are all Fulani's.
@okodogbegraceolapeju1021
@okodogbegraceolapeju1021 4 күн бұрын
Fulani ni Adajo, ohun nuu, Olorun nuuu
@RebeccaOyelolaCSI1-lc8rn
@RebeccaOyelolaCSI1-lc8rn 4 күн бұрын
Favoritism re o😭
@olaajibola1097
@olaajibola1097 4 күн бұрын
Aamin,so shall it be.
@olaiyapeter1043
@olaiyapeter1043 3 күн бұрын
Osun state ni emi wa o. Ọmọ Fúlàní ni ogbimọ pọ pẹlú àwon ọrẹ rẹ.ti won ji bàbá rẹ gbé. Fúlàní ni gbogbo awọn tí wọ́n dajọ ikú fún. Kòsí yoruba kankan nínú awọn apànìyàn yi o. Ejeki ama wadi òhun gbogbo daju.
@OluwatobiAdunni
@OluwatobiAdunni 4 күн бұрын
So sad
@kayodeadebayo3447
@kayodeadebayo3447 4 күн бұрын
Pelu Oruko awon enia ti eda oruko yen o dabi pe Fulani ni awon enia na
@margaretalonge1220
@margaretalonge1220 4 күн бұрын
Amin won oo ni Jere
@susannahopeogunbanwo5200
@susannahopeogunbanwo5200 4 күн бұрын
Amen
@AdebayoSulaimon-ee6zh
@AdebayoSulaimon-ee6zh 4 күн бұрын
Yeye dara o ti ye ko ye awon omo yoruba pe fulani ni o ndari wa se adajo ko ri ti wakil won ri ejo wakili da di oni awon ni yen oloun a mu gbogbo won
@margaretadebiyi8858
@margaretadebiyi8858 4 күн бұрын
Ase wa 🙏
@blessingbless3941
@blessingbless3941 4 күн бұрын
Amen it shall not be well with them all
@margaretibijoke4973
@margaretibijoke4973 4 күн бұрын
Oku aye ni awon tin dari Nigeria 😢😢
@amosomotunde9341
@amosomotunde9341 4 күн бұрын
Haaaa wahala nla re o kilode ti awon adajo yi o le dajo iku fun awon headsmen tiwon npa awon eniyan nile yoruba??? ati daran nile yoruba haaa ile to lo yoruba nation nowww
@modupekosoko1176
@modupekosoko1176 4 күн бұрын
Alabode ni adajo yin oo
@jameseniolorunda3825
@jameseniolorunda3825 4 күн бұрын
Politics has eaten us too deep ni , that adajo would have been friends with them
@user-vw9hv5ie9o
@user-vw9hv5ie9o 3 күн бұрын
Oloriburuku ni adajo yen awon Fulani lo ma pada pa oun gan na..
@olayinkaadesina1394
@olayinkaadesina1394 4 күн бұрын
They we not go unpunished it's uncorfor the jugdement will be nullify and canceled by fire.Ko jo.
@gbemisolalawal5758
@gbemisolalawal5758 4 күн бұрын
Ase wa
@fehintolacomfortsolesi6519
@fehintolacomfortsolesi6519 3 күн бұрын
Sugbon ko ye rara. Ki adajo yen se be at all. Ti orire ba pe.
@oladiran4707
@oladiran4707 3 күн бұрын
Okan ninu awon omo ale ile yoruba ti foju han gbangba bayi o. Awon fulani npa ogun won npa ogban, ako ri enikeni mu ninu won, belentase pe won yoo mu won lo sewon. Haa.. adajo yi ti fi ogun Jawa. Idajo yii ko gbodo duro. Ika eniyan gbaa ni Adamo yii.
@Dammykolawole1
@Dammykolawole1 3 күн бұрын
I knew governor ademola will not know all this now
@JohnWasinuola
@JohnWasinuola 4 күн бұрын
Haaaaa omaseun
@bukolayussuf862
@bukolayussuf862 4 күн бұрын
Omg
@margaretalonge1220
@margaretalonge1220 4 күн бұрын
Haa!!!
@rasaqraji5640
@rasaqraji5640 4 күн бұрын
Adajo yen ti gba owo lowo FULANI olorun yo tun ejo na da ,Adajo eke Ole
@user-vw9hv5ie9o
@user-vw9hv5ie9o 3 күн бұрын
Adajo yen olori buruku ni , Iran Fulani si ni..
@victoriamodupe7896
@victoriamodupe7896 4 күн бұрын
BOYA AWON NA NI WON KO AWON CATTLES REARING YEN FUN AWON FULANI WON YEN LATI MA BA WON MA SHI MR JUSTICE IN OSHUN STATE. HIGH COURT. PLEADE6. WE ARE HUNGER. HUNGER. POVERTY. IN SOUTHWEST OF NIGERIA PLEASE
@christopherodemikhe639
@christopherodemikhe639 4 күн бұрын
Good talk, madam
@adeyemi9741
@adeyemi9741 4 күн бұрын
Hmmmmm 😭😭😭😭😭 I just want to forgot this country Nigeria and Yoruba nation, our leaders in Yoruba land are the problem.
@Dammykolawole1
@Dammykolawole1 3 күн бұрын
Eni adanu ni won.. Won ni leyin ire
@okodogbegraceolapeju1021
@okodogbegraceolapeju1021 4 күн бұрын
Ase
@Abdullahi-pf1lu
@Abdullahi-pf1lu 4 күн бұрын
😭😭😭😭❤❤❤
@jokeakinfewa385
@jokeakinfewa385 4 күн бұрын
IKu OJIJi Lo ma pAWON AMEN
@olumuyiwakehinde929
@olumuyiwakehinde929 4 күн бұрын
E Fi photo adajo yen sita fun gbogbo aye. Ejo yeye Dara. O tunmo si pe gbogbo fulani ni a ma se idajo iku fun
@gbengamabadeje4038
@gbengamabadeje4038 4 күн бұрын
Olorun adajo afi eyin peran
@AdebayoSulaimon-ee6zh
@AdebayoSulaimon-ee6zh 4 күн бұрын
Ase edumare be ti wi lo ma ri were ni awon adajo Nigeria won ari otito won ni so
@adebolaololade6354
@adebolaololade6354 4 күн бұрын
Oloribuku ni adajo na iya yi po
@susannahopeogunbanwo5200
@susannahopeogunbanwo5200 4 күн бұрын
Who's this judge?
@rasheedakangbe3697
@rasheedakangbe3697 4 күн бұрын
DO THESE CONDEMNED PEOPLE HAVE OPTIONS OF APPEAL.? WHEN DID THEY ARRIVE AT DEATH SENTENCE? HOW DID THIS CRIME GOT DEFINED AS FIRST DEGREE OFFENSE?
@user-or9ge2wu4k
@user-or9ge2wu4k 4 күн бұрын
Atubotan adajo yen koni daa koni foworori ku lagbara Olorun
@user-yw3iy7iu6w
@user-yw3iy7iu6w 4 күн бұрын
A tuber of this at mile 12 is #13, 000 . No shaking ?.
@RemilekunAdeleye-ew4dp
@RemilekunAdeleye-ew4dp 4 күн бұрын
HAHAHA
@Dammykolawole1
@Dammykolawole1 3 күн бұрын
Five yoruba future
@AkinyemiFrancis
@AkinyemiFrancis 4 күн бұрын
Hahaha
@amodustephen6619
@amodustephen6619 4 күн бұрын
Yeye Dara kokooko, E ma sepe mo, sugbon , eyi ti E se yen aran a ro mon. That's ridiculous, oburu ko se gbo seti
@d-blisstv3214
@d-blisstv3214 4 күн бұрын
How true is this?
@adeniyijimoh6980
@adeniyijimoh6980 4 күн бұрын
Awa Omo Yoruba ma nberu Fulani t'abi Awusa.
@olumike9935
@olumike9935 4 күн бұрын
Very difficult to believe, I think the Judge or whatever he’s called is not of this world 😡
@toyinruka64
@toyinruka64 4 күн бұрын
Oleje Ada modi yoruba ni adajo yen pelubi fulani Sen pa yoruba to
@victoriamodupe7896
@victoriamodupe7896 4 күн бұрын
WE. ARE HUNGER. HUNGER IN SOUTHWEST OF NIGERIA CITIZENS PLEASE
@adiituorotv
@adiituorotv 4 күн бұрын
Please give us the full details
@olusanyaorebe2932
@olusanyaorebe2932 4 күн бұрын
Oriburuku maa ba gbogbo won
@user-yv1ze4tm6e
@user-yv1ze4tm6e 4 күн бұрын
Ere ni won se won jeda ejo oribu beye no gbati won yawere
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 4 күн бұрын
Ki adajo yen ki oma mura sile Omo Yoruba Bo fun. Ki o pa awon marun kari na. Lati odun ti Fulani ti pa Omo Yoruba. Adajo kankan kori ejo da. to ba je ogun ni amaja. Yoruba must free. Adajo high Court in osun state if dey kill that 5 farmers you no go free
@funmicole479
@funmicole479 4 күн бұрын
Fulani Don tell ths politicians to lie to us to get into power n thn thy change
@adeolajoshua371
@adeolajoshua371 3 күн бұрын
They should not uphold that Judgement in our land or else they will arouse the angers of the youth in yoruba land. It's very unfair, what of the people who have been killed by the Fulani herdman's.
@victoriamodupe7896
@victoriamodupe7896 4 күн бұрын
THE WHOLE WORLD NI WON MO WITH. AWON NIGERIAN GOVERNMENT. BERU AEON FULANI. .. E TUNBO MU SURU KI WON PA GBOGBO YIN TAN NITORI. VANITY UPON VANITY. AWON OJELU GBOGBO TI WON KU NILE YORUBAS NKON WON KU PELU ORUNKO WON NI. AWON WO NI WON RI TI AWON OMO WON RO ..WON JERE ISE OWO AWON OBI WON GBOGBO NI
@Dammykolawole1
@Dammykolawole1 3 күн бұрын
We no hear about the corper again now and the illiterate is moving around aye awon agba ile including governor yoruba ti baje...
@estherewetuga8245
@estherewetuga8245 4 күн бұрын
Eleyi tun ga o
@olatemitope737
@olatemitope737 4 күн бұрын
Guys are we sure our ppl are not collecting money from these ppl to graze on their farm? Because this has been going on for long and nothing has been done by the farmers.
He sees meat everywhere 😄🥩
00:11
AngLova
Рет қаралды 11 МЛН
Вечный ДВИГАТЕЛЬ!⚙️ #shorts
00:27
Гараж 54
Рет қаралды 14 МЛН
EEGUN ALAPANSASNPA NI ILU IBADAN
13:28
Isedale Abinibi Wa
Рет қаралды 9 М.
OBA GHANDI OGBOMOSO
56:58
Itan Yoruba
Рет қаралды 8 М.
Samuel Ladoke Akintola
11:11
Isedale Abinibi Wa
Рет қаралды 12 М.
Message for Kola olootu, Muideen and Agbala Gabriel
19:04
Tani Olohun
Рет қаралды 12 М.
🤣МАЛО КУПИТЬ ЛОШАДЬ
0:18
Бутылочка
Рет қаралды 1,7 МЛН
谁能救救小宇宙?#火影忍者 #佐助 #家庭
0:43
火影忍者一家
Рет қаралды 3 МЛН
Многие думали что Фёдору конец!
1:00
МИНУС БАЛЛ
Рет қаралды 1,3 МЛН
BABY Comedy : Gift for baby💔
0:41
BABY Comedy
Рет қаралды 6 МЛН
ToRung short film: 🎁special gift❤️
0:49
ToRung
Рет қаралды 13 МЛН