@COVENANT OF MERCY DISCLAIMER!!!! We own no copyright license for all Music used on this program. We give credit to the music owner, producer, and record label.
Пікірлер: 37
@bilikisuamoje940427 күн бұрын
Amin amin amin amin amin amin amin
@samsonoluwasola751127 күн бұрын
More anointing in Jesus name 🙏 🙌 ❤ ✨ 💖 💕 🙏 🙌 ❤ Amen 🙏.
@bilikisuamoje940427 күн бұрын
Amin JESU KRISTI and my children in JESUS CHRIST NAME AMEN AMEN
Oluwa ki ile oni to su, je ki n ri aanu gba, ki ile oni to su, je ki awon omo mi ri aanu gba nibi gbogbo, lowo awon to feran mi Oluwa je ki nri aanu gba, je ki awon omo mi ri oore nla gba lowo awon to fe won, fi aanu gbe mi dide, lowo oga ati awon omo ise je ki n ri aanu gba ki ile oni to su loruko Jesu
@AkinyoyenuAbike27 күн бұрын
Fi aanu wa mi ri Oluwa 💃💃💃💃
@amiradib685527 күн бұрын
❤💖🙏💖❤
@adeyemiileaje423827 күн бұрын
Ero buburu ota lori aye mi ati awon omo mi, Oluwa yi danu, Oluwa da pada le won lori
@abayomiabogunrin24427 күн бұрын
❤❤❤❤🎉🎉🎉
@oluwabankejoshuaomoayegbo27 күн бұрын
Funny Daddy 🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣
@adeyemiileaje423827 күн бұрын
Ni oruko Jeeesu Olorun aaanu oooo, saanu mi ooo, mo nilo aanu re, awon omo nilo aanu re, saanu fun mi tomotomo, saanu fun mi tiletile, saanu fun ati awo ololufe mi gbogbo, fowo aanu re kan mi tomotomo, fowo aanu re gbe mi dide tomotomo, aanu ni mo fe ooo, fi aanu silekun oore gbogbo fun mi ati awon omo mi loruko Jesu