Orin Ojowubinrin by Ogundare Foyanmu | ODEC 47

  Рет қаралды 5,848

AIF YORUBA CULTURAL CENTRE

AIF YORUBA CULTURAL CENTRE

3 жыл бұрын

Nínú àwo rẹ́kọ́ọ́dù yí ni ọ̀jọ̀gbọ́n Ogundare Foyanmu tí kọrin lórí àwọn wọ̀nyí:
JAGUNJAGUN BẸNJAMẸ́Ẹ́NÌ ADÉKÚNLÉ
ORIN ÒJÒWÚ OBÌNRIN
Ọ̀RẸ́ Ọ̀DÀLẸ̀
Awítúnwí akùdé gbólóhùn jẹyọ nínú ewì Ọ̀RẸ́ Ọ̀DÀLẸ̀. Níbẹ̀ ni Foyanmu ti ṣàpẹẹrẹ ìwà àwọn ènìyàn kan láwùjọ, tí ìlú yóò lérò láti gbé wọn sípò tó ga, ṣùgbọ́n tó jẹ́ pé ìwà tí irú nnkan bẹ́ẹ̀ yóò se fò wọ́n ru ni wọ́n máa hù.
"À lá á fewúrẹ́ joyè, ewúrẹ́ ń jewé ọdán
À lá á fàgùtàn joyè, wọ́n à si maa jẹ ìyẹ̀fù
À lá á f'ológínní joyè òkè, àjà ní n fò fẹrẹ"
Ogundare Ayano, ọmọ wọn ní Ilé Foyanmu, Taràá, Ogbomoso gbé ki Jagunjagun Bẹ́ńjámínì Adekunle tí òun náà jẹ́ ọmọ Ogbomoso ṣùgbọ́n ó ti di olóògbé báyìí.
Ogundare Foyanmu nínú ká fi ewì ṣe àpọ́nlé ènìyàn, ó ṣe àpọ́nlé Ajagunfẹ̀yìntì BẸNJAMẸẸNI ADEKUNLE púpọ̀ gbáà. Pàápàá jù lọ bí ó ṣe jagun gba Nàìjíríà sílẹ̀ lọ́wọ́ ogun Biafra tí Ojúku gbé dìde.
Bí ẹ bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa Ogundare Foyanmu àti àwọn orin Ìjálá tó ti kọ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọn, ẹ ríi pé ẹ ra ìwé tí 'ṢAYỌ̀ ALÁGBÈ kọ tí a pè ní ÌJÁLÁ OGUNDARE FOYANMU (ÌJÌNLẸ̀ ÈDÈ OHÙN ẸNU YORÙBÁ).
For more information about Ogundare Foyanmu and insight into his Aré Ìjálá Ọdẹ, make sure you buy a book written by 'ṢAYỌ̀ ALÁGBÈ called ÌJÁLÁ OGÚNDÁRE FỌ́YÁNMU (ÌJÌNLẸ̀ ÈDÈ OHÙN ẸNU YORÙBÁ)
AIF MEDIA is where we tune lives with tongue and culture. AIF MEDIA is a medium with passion to unite Yorùbá people to their heritage; promote and preserve godly virtues from Yorùbá culture, tradition and lifestyle; and give poetic admonitions.
Our networks:
YÒRÙBÁDÙNLÉDÈ | ÌTUMỌ̀ | BIBLICOPOETRY
Enjoy our educational videos!
To learn more about us, please visit our website.
FACEBOOK
bit.ly/AIFMEDIA-Facebook
TWITTER
bit.ly/AIFMEDIA-Twitter
INSTAGRAM
bit.ly/AIFMEDIA-Instagram
Watch, subscribe and share with others.
#aifmedia #ijala #foyanmu #ogbomoso #sayoalagbe #ogundarefoyanmu #yorubapoetry #yorubaliterature #yorubaresearch #yorubapoem #ewi #areode #jagunjagun #benjaminadekunle

Пікірлер
Ija Ore Meji, Oriki Ijesa and Oriki Ibeji by Ogundare Foyanmu
35:09
AIF YORUBA CULTURAL CENTRE
Рет қаралды 10 М.
Ouch.. 🤕
00:30
Celine & Michiel
Рет қаралды 23 МЛН
What it feels like cleaning up after a toddler.
00:40
Daniel LaBelle
Рет қаралды 89 МЛН
7 Fatiha 7 Ayetel Kürsi 7 İhlas 7 Felak 7 Nas Kur'an-ı Kerim Rukye
24:23
fussilet Kuran Merkezi
Рет қаралды 77 МЛН
Ogundare Foyanmu (Ikini Nile Yoruba) Side One
16:36
Olatunbosun Oladapo Akewi - Topic
Рет қаралды 1,8 М.
Egun Iponriku history (war masquerade )
18:10
Ebony TV
Рет қаралды 2,6 М.
Notable Moments from Oba Ghandi Olaoye Orumogege III Coronation in Ogbomoso
40:30
AIF YORUBA CULTURAL CENTRE
Рет қаралды 6 М.
Oriki Olodumare by Ogundare Foyanmu
16:48
AIF YORUBA CULTURAL CENTRE
Рет қаралды 23 М.
Zeynab -Mogba Ara Da (Bolojo)
4:46
Zeynab
Рет қаралды 425 М.
Awon Obinrin
16:35
Olatubosun Records
Рет қаралды 42 М.
Jesu (Jesus) Chant | Worship With Me | Toluwani Odukoya
6:09