ORO RE O SI CHIEF IMAM OGBOMOSO LORI OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE SOUN OF OGBOMOSO

  Рет қаралды 3,175

DriveTv News

26 күн бұрын

ORO RE O SI CHIEF IMAM OGBOMOSO LORI OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE SOUN OF OGBOMOSO
SUBSCRIBE HERE👉 goo.gl/ypvoyF
YORUBA NEWS CHANNEL SUBSCRIBE HERE👉 kzfaq.info/love/SVLmN-AX5nut78ib27668g
- Drivetv news
- www.drivetvnews.com
Imam Teliat Yunus Olushina Ayilara II
Oba Ghandi Afolabi Olaoye
follow us on
FB:- @drivetvnews
IG:- @drivetvnews
TWEETER:- @drivetvnews

Пікірлер: 23
@abiolatijani621
@abiolatijani621 26 күн бұрын
Ododo oro odabi isokuso ni oko eleha mo gba fun yin olorun ase Alekun imo yin sir
@user-rq8cv9op7c
@user-rq8cv9op7c 26 күн бұрын
You are correct sir
@olusolaogungbile4648
@olusolaogungbile4648 26 күн бұрын
Baba yi ti jeki esin musulumi wumi,tele mi manro wipe gbogbo Awon elesin musulumi ni oni jagidi Jagan, sugbon pelu Oro Alfa yii haa,esin Islam Dara,awon Miran ninu ijo musulumi lo buru 😮 tiwon Fe ba esin yen je, olohun o sini gba fun won lati ba esin yen je.
@muriadisa2306
@muriadisa2306 26 күн бұрын
Who dey look for you in Islam
@olusolaogungbile4648
@olusolaogungbile4648 26 күн бұрын
@@muriadisa2306you're the enemy of progress.
@SirG_world
@SirG_world 22 күн бұрын
He can not listen to your advice because he is the one inviting those people, you are protecting your own King because you are true son of ikire, you are Weldon sir
@rachealolaifa542
@rachealolaifa542 26 күн бұрын
Walai,onigberaga ni lmam Ogbomosho Yi,ko ni pe subu lagbara Olorun ati awon onile.from day 1,Lo ti nbuu Kabiyesi,IWA omo Ale ti won pe lo nhuu. Shee esin lo nse Yi,abi Esin?
@jimohadewale4344
@jimohadewale4344 26 күн бұрын
Awon irandiran re lo ma subu
@omolewabello3467
@omolewabello3467 26 күн бұрын
Ko mature ko si mo itumo maturity Abuku nipe imaam ati oba nja se towo ni abi ti ipo
@ditty6828
@ditty6828 26 күн бұрын
Alfa Komadun, toliat o le gbo tori kii se omo Ogbomoso.
@folashadetaiwo939
@folashadetaiwo939 25 күн бұрын
Baba wa Alifa komadun, O ma ma dun fun yin tomo tomo ati ebi yin titi lae lae, e ku atunse, e tubo ma bawa fona otito han awon alakatakiti oni jagidijagon esin gbogbo wa loma jiyin ise wa fun Baba loke,
@omolewabello3467
@omolewabello3467 26 күн бұрын
Oun ko lo ni baba nitoripe oun lo gbe enieleni le awon were Alfa lowo Ti e ba tun gbo ohun ti ikan ti won pe ni Taofeek carpenter tun so nipa oba yi e mo pe opolopo awon Alfa Yi ko ti Ile re wa,won o si ni aso gidi Lori Iko Yunisa toliat lo pe won wa ki won o maa wa ba oun bu oba To ba je omo Ogbomosho tooto ko ni maa koawon tug Alfa lati da ilu Ogbomosho ru
@ditty6828
@ditty6828 26 күн бұрын
Exactly.
@fataihonest
@fataihonest 26 күн бұрын
Awon Were afa lowa nita ni sin yi
@user-tv8kh6qm4r
@user-tv8kh6qm4r 24 күн бұрын
Olorun ko ni pada leyin yin sir. I will like to have your number
@oluseyeojo3726
@oluseyeojo3726 26 күн бұрын
Nigbati yoruba ba gba ominira alfa eni dawati.
@dadagabriel6444
@dadagabriel6444 26 күн бұрын
Amin Amin Amin 👍👍👍👍
@peterfernandez7511
@peterfernandez7511 26 күн бұрын
Se bi eri wipe awon Christeni o jade waja awon musulum ati alfa ni ija KABIYESI oba loma Bori won.
@sammysol61
@sammysol61 26 күн бұрын
Imamu Ogbomosho is an ARROGANT person. He finds it difficult to separate religion from humanity. E ba imamu soro ko huwa irele. Igberaga ni major problem imamu Ogbomosho. He has insulted Baba Akewu gba Gold ati awon bebee. Igbagbo mi ni wipe iwa igberaga ti imamu Ogbomosho ni lo je ki awon ebí re o ko eyin si. E ku eto. E ku ifi ti omoniyan se. Oke oke le o maa lo. Otito ati igboya yio si maa gbeyin bori gbogbo awon alatako otito.
@nathaolu5600
@nathaolu5600 26 күн бұрын
Olorijakujaku-jagajaga ni fake mufti Iwo. Agborodun apaniyan jatijati ni fake mufti Ilu Iwo
@adeyemifolake3468
@adeyemifolake3468 26 күн бұрын
Ki imam yen lo bo aso igbraga ti o wo yen Sonu, ko fi ola fun eniti ola to si, ko lo tun Ara re se lodo awon ebi re
@ditty6828
@ditty6828 26 күн бұрын
Ko le so si odo won tori o mo pe oun kii se ara won. Nitori e lo se damu to si ngbogun ti oba.
@BoseAdebayo-dy1dt
@BoseAdebayo-dy1dt 26 күн бұрын
Baba yi yio dara fun O tomo tomo. Were Alfa kan lati Iwo towa gunfe were ti o nfoba wa sepe , Awa o Fe wahala ni, sugbon bi Oluwa ti wa ti emi re wa egun wole Alfa were yen Tori Oba wa koto si epe to fi won se. A da pada sori re ati idile re lagbara Olorun
How Many Balloons Does It Take To Fly?
00:18
MrBeast
Рет қаралды 195 МЛН
Secret Experiment Toothpaste Pt.4 😱 #shorts
00:35
Mr DegrEE
Рет қаралды 34 МЛН
How Many Balloons Does It Take To Fly?
00:18
MrBeast
Рет қаралды 195 МЛН