Пікірлер
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx Күн бұрын
Beeni iya wà e seun pupo.a ku ojumo ose yi atuwa Lara anu, ojurere.ore -ofe Jesu a bawa rin larinye a nishirin ani Shi so ni oruko Jesu
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 Күн бұрын
@@rachaelokediji-hv2bx 🙏🙏🙏🙏 Ẹ ṣeun púpọ̀ o, ìyá wa
@johnemmanuel7217
@johnemmanuel7217 8 күн бұрын
Please how can i get the books
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 7 күн бұрын
Ẹ kàn sí Bàbá lójú òpó Facebook wọn Sulaymon Raji @@johnemmanuel7217
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 16 күн бұрын
E seun pupo iya wà Ohun yin o ni ha a lase olodumare.a Ku ojumo ose yi atuwa Lara anu olorun abawa rin larinye.ohun gbogbo a rorun fun wa ni oruko Jesu ❤️
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 15 күн бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o, ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx
@folorunshoabiola165
@folorunshoabiola165 20 күн бұрын
Ejowo bawo ni mose le ri iwe yi ra
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 20 күн бұрын
Ẹ kàn sí Bàbá lójú òpó Facebook wọn Sulaymon Raji @@folorunshoabiola165
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 22 күн бұрын
E seun pupo iya wà,Ka maa joye a danikan je,Iwo ni emi ni ni je o sekun
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 21 күн бұрын
Ẹ ṣeun o, ìyá wa @@rachaelokediji-hv2bx
@Imctv2022
@Imctv2022 Ай бұрын
Happy birthday Aláyélúwà
@TosinAnimashaun
@TosinAnimashaun Ай бұрын
Hmm... "A kìí dákẹ́ ṣì wí A kìí rò [UNCLEAR] dáràn ... Ohun tó sì wí báyìí làá wí Kò sí ẹni tó máa ń sọ pé ohun tó fẹ́ sọ rèé." Ẹ dákun, kí ni ẹ sọ ní apá ibẹ̀yẹn? Ẹ ṣéé.
@AbigailoyelolaOnifade
@AbigailoyelolaOnifade Ай бұрын
Mansulo laya Olugbala Ajala Aagbe
@norseman6819
@norseman6819 Ай бұрын
Ogbagi is not Ekiti and not part of Ekiti state. Ogbagi is Akojo Ondo state
@TaiwoAminat-dy6yd
@TaiwoAminat-dy6yd Ай бұрын
Eyin alfa nitori olorun.abawaye onikaluku se ototo
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx Ай бұрын
Huuuuuu ododo Oro Ohun yin oni ha lase Edumare..eniyan buru o pupo e seun iya wa
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 Ай бұрын
Ẹ kú ìmọyì rẹ̀ o ìyá wa
@alaosunday9274
@alaosunday9274 Ай бұрын
Hummm
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 Ай бұрын
👍
@ayyubsolahudeen8652
@ayyubsolahudeen8652 Ай бұрын
You didn't talk about ayajo
@howolabihhowolabih1856
@howolabihhowolabih1856 Ай бұрын
This are my mother family that woman wearing white is my mom senior sister 😮
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 Ай бұрын
👍👍
@adelekemicheal8520
@adelekemicheal8520 2 ай бұрын
Agba yin a dale Baba
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 2 ай бұрын
Àmí o, ẹ ṣeun púpọ̀.
@abdulkarimsalman
@abdulkarimsalman 2 ай бұрын
Eku igbiyanju Oluwa alaanu julo yio sanyin lesan daradara Akintola akinkanju okunrin,sun re ooooo, Ogbomoso ko ni baje lase edumare ❤
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 2 ай бұрын
E seun pupo mo gbadun itan dowe yi gan ni eni tenu gbo bi owo lase Edumare..a se jere ni tiwa ni oruko Jesu ❤️
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 2 ай бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà
@alaosunday9274
@alaosunday9274 2 ай бұрын
Hummm, isi'ti.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 2 ай бұрын
Ẹ kú ìmọyì rẹ̀ o
@alaosunday9274
@alaosunday9274 2 ай бұрын
Ooto oro. I can recognize it.
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 2 ай бұрын
E seun pupo itan Ohun dun po eni Shi so olorun a mu yiñ mo Moke sii ni oruko Jesu
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 2 ай бұрын
Àmí lórúkọ Jésù Kristi.
@ruser0084
@ruser0084 3 ай бұрын
E ku ise
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 2 ай бұрын
Ẹ ṣeun o
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 3 ай бұрын
Húuuú Oro nla a Ku ojumo ose yi adara funwa Ohun gbogbo a rorun fun wa ni oruko Jesu ❤️
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 3 ай бұрын
Àmí lórúkọ Jésù Kristi. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà
@labakefunmi7319
@labakefunmi7319 3 ай бұрын
From Abuja
@mikeplucy2000
@mikeplucy2000 3 ай бұрын
Olorun ko ni je ki Yoruba tun ri iru Samuel Ladoke Akintola mo ni ipinle iwo orun not Nigeria. Amin ati Amin. Lately, certain uninformed man said that”Akintola did not betray Awolowo” The person is young and informed. The truth was: Akintola Betrayed Sons and Daughters of Yoruba race.
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 3 ай бұрын
Beeni e seun pupo olorun a maa fun yin so o amu ogbon yin ko fo o lase olodumare..ose yi adara funwa ni oruko Jesu❤
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 3 ай бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa
@alaosunday9274
@alaosunday9274 3 ай бұрын
Hummm e se
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 3 ай бұрын
Ẹ kú ìmọyì rẹ̀ o
@gboyegabisileko8585
@gboyegabisileko8585 3 ай бұрын
E seun pupo.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 3 ай бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@mubarakadebambo9087
@mubarakadebambo9087 4 ай бұрын
Káábíèsí has explained even better than most teachers.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
Ẹ kú ìmọyì rẹ̀ o
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 4 ай бұрын
E Ku Ohun eni Shi so lase olodumare
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa
@omolaraoluranti2254
@omolaraoluranti2254 4 ай бұрын
Ami,Ase Edumare
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o ìyá wa pàtàkì 😘
@ewaedeatiasayorubaponnbele2340
@ewaedeatiasayorubaponnbele2340 4 ай бұрын
Àmí Jésù 🙏..... Mo mọ̀ ọ́ lóore iyekan mi
@akintundeokelade2563
@akintundeokelade2563 4 ай бұрын
Yoruba culture and traditional heritage is rich and meaningful. Thank you all.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
👍👍
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 4 ай бұрын
E Ku irin e Ku ise obirin bi okunrin olorun koni fiyinsile ariye ni oruko Jesu
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
Àmí lórúkọ Jésù Kristi. Ẹ ṣeun púpọ̀ mà
@alaosunday9274
@alaosunday9274 4 ай бұрын
Baba's dancing steps and the drums are for me. Yoruba has no equal
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
✌️✌️✌️✌️
@alaosunday9274
@alaosunday9274 4 ай бұрын
The anchor looks like Afolayan
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 4 ай бұрын
He is
@historywitharewa1630
@historywitharewa1630 5 ай бұрын
I am very very disappointed and also ready mad at this king , does he even worth to be called a king of an important ancient town . This is really shameful. A whole king doesn't know the history of the throne he is on , imagine saying ladigbulo gave birth to aalafin abiodun . He doent deserve nor meant to be on that throne .
@olowonimy9261
@olowonimy9261 5 ай бұрын
Well baba tried he got some story it's not easy like that kodus to you
@olowonimy9261
@olowonimy9261 5 ай бұрын
All the stories is not genuine
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 5 ай бұрын
Aaaaaase ooooo a Ku ojumo ose yi adara funwa ni oruko Jesu
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
🙏🙏🙏
@alaosunday9274
@alaosunday9274 5 ай бұрын
Amin Edumare oooo
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
🙏🙏🙏
@princessadetutu3665
@princessadetutu3665 5 ай бұрын
Thanks for sharing ma God bless you OSOSA ONI BAJE ASE
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@AREMUAKEWITV
@AREMUAKEWITV 5 ай бұрын
❤❤❤❤
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Ẹ ṣeun o
@AREMUAKEWITV
@AREMUAKEWITV 5 ай бұрын
❤❤❤❤
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Ẹ ṣeun o
@rachaelokediji-hv2bx
@rachaelokediji-hv2bx 5 ай бұрын
Huuuuu yio Ku Ku da a ni oruko Jesu
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Àmí o oo. A ṣá kú àsìkò yìí
@kehindeandu4040
@kehindeandu4040 5 ай бұрын
Olorun seun o ❤
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
❤️❤️❤️
@olatunbosunoladapo
@olatunbosunoladapo 5 ай бұрын
FARE THEE WELL BROTHER JIMMY SOLANKE
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Ẹ kú àṣẹ̀yìndè wọn o, Bàbá mi
@taiwohassanfolorunso7023
@taiwohassanfolorunso7023 5 ай бұрын
Your story telling was not cognitive , sorry
@johnsonolajide4647
@johnsonolajide4647 5 ай бұрын
Well said 👍💯 percent
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 5 ай бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@IMCTV-me4jn
@IMCTV-me4jn 6 ай бұрын
Happy birthday Prof.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 6 ай бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o
@alaosunday9274
@alaosunday9274 6 ай бұрын
Imoran gidi.
@isedaleabinibiwa2020
@isedaleabinibiwa2020 6 ай бұрын
Ẹ ṣeun púpọ̀ o