I like your presentation, you present lite you are telling a folk tale story.
@SamsonAboderin
Same to all of them.the young shall grow
@OlarewajuJuliana-u8w21 күн бұрын
Alale Yoruba ko ni jeki asiri awon obaye je omo Yoruba ki o bo
@AdeyemiAderemi-ft8wj
Omoyale is the first person
@mayowaaliu1176
What a shame on gani Adams, he is a political aare ona kakanfo
@user-lg9xf9ds4r
But bawo wa ni gani Adam se ba okunrin je ni kootu tie wa ko sori platform yin,
@user-mi5lw8sj9v
@ Gani Adams Ati Awon Omoeyin Re Wa Pinnu Lokan Arawon Lati Ma Gbogun Ti Awon Olotito Omo Yoruba.. Kinlode Gan? Ibiti Ija Ilara Ma Nyori Si Naa Niyan..
@princeland1249
I pity Gani Adams for what he did, he may later regret is action because is not only Sunday igboho is fighting with oo he is fighting with all Yoruba people
@omolajapaultaiwo6414
O better ki Gani Adam be awon agbalagba,nile Yoruba ki won ba won pari e
@user-ot9wg1tm3k
Konidafune ATI gbogbo eyin elewon ti E ntele 419 Sunday dagboru ehoro, Ibo ni court ti E PE EJO si, werrey nseyin, eyin Ole Nation
@gilbertadeyemi3674
Iba logunojo
@pauloladele7812
Ai nironu lo nda yin laamu, ati pe epe Afonja lo njaYoruba. Yoruba e ronu koiti peju.
@user-ot9wg1tm3k
E ntanrayinje, Case eyin ATI werrey babayin Sunday ehoro kunle repete, E nshiere
@JacobAdumadeyin
Bibeli so wipe ohunkohun ti eniyan base labe Orule Ori Orule ni aoti gbo kosi ase gbe asepamo lowa
@OdunsolaGbenga
Yoruba eyi pada
@SakaLateef-im4gd
Hmmm 🤔
@joelbalogun9254
Emi gege bi omo yoruba ti awon obi mi baba ati Iya na si je omo Yoruba, fi tinutinu mi ni igbagbo pe Eni bi, alaimore, olote, Ota Yoruba ni Gani Adams. Se bi igbati Gani fi nwuwa omota thug tondaluru,ti ijoba fi gbe ti won ju si ewon, sebi omo yoruba lo ja fun ti won fi yo kuro ninu ewon. Omo yoruba lo fi je Are one kakanfo, ile yoruba lo ti ri owo to fi je eniyan lo ni.
@nelsonadenola9754
He made mention of President Tinubu, Tayo Ayinde, and Chief Sunday Igboho. Pretty soon, Jagaban will invite him over...then he will know that he who keeps his mouth keeps his life.
@colacoke4640
Almost 2 month now, where is the case. Tayo Ayinde and tinubu knows the letter is real. They can't go to any court because those that write the letter will be in trouble
@IsiakAdemolazico
You and your boss igboho are mad,eniti olorun gbega to iru eyin wereyi ropeelegbe subu,iro lefiyenpa